Skip to content Skip to sidebar Skip to footer

(DOWNLOAD) "Ìkẹtàlá Ti Megan" by Owen Jones " Book PDF Kindle ePub Free

Ìkẹtàlá Ti Megan

📘 Read Now     📥 Download


eBook details

  • Title: Ìkẹtàlá Ti Megan
  • Author : Owen Jones
  • Release Date : January 13, 2021
  • Genre: Paranormal,Books,Sci-Fi & Fantasy,Fantasy,Fiction & Literature,Ghost,
  • Pages : * pages
  • Size : 526 KB

Description

Ìkẹtàlá Ti Megan ni ọ̀wọ́ kejì nínú mẹ́tàlélógún ti Ipele Megan. Ó jẹ́ ọjọ́ ìbí Megan tí ó ní agbára nínú ẹ̀mí. Láti ṣe àjọyọ̀ rẹ̀ pé ó da ọ[dọ́, àwọn òbí rẹ̀ nṣe àpèjẹ nlá kan fún u. Tẹbí tọ̀rẹ́ ni wọ́n pè síbi ayẹyẹ nlá náà, níbi tí olùṣètò orin tí ó jẹ́ akọni rẹ̀, Jack Hammer yóò ti gbé àwọn orin jáde. Ó ndà á rò bóyá ẹnikẹ́ni fi ojú sọ Grrr, àléjò rẹ̀ nlá tíí ṣe ànjọ̀nnú Ẹkùn ará ilẹ̀ Siberia. Kò máa níi ́lọ́kàn láti pàdé àlejò kan tí ó rẹwà lọ́kùnrin. Ipele Ti Megan wà fún àwọn ènìyàn láìfi ti ọjọ́ orí ṣe tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ ti ẹ̀mí.


Free Books Download "Ìkẹtàlá Ti Megan" PDF ePub Kindle


Post a Comment for "(DOWNLOAD) "Ìkẹtàlá Ti Megan" by Owen Jones " Book PDF Kindle ePub Free"